Native Bible

Numbers 1:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti ọ̀dọ̀ Gadi, Eliasafu ọmọ Deueli.

Numbers 1:14 in English

Numbers 1:14 · Berean Standard Bible

from Gad, Eliasaph son of Deuel;

Context

12Láti ọ̀dọ̀ Dani, Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai. 13Láti ọ̀dọ̀ Aṣeri, Pagieli ọmọ Okanri. 14Láti ọ̀dọ̀ Gadi, Eliasafu ọmọ Deueli. 15Láti ọ̀dọ̀ Naftali, Ahira ọmọ Enani.” 16Àwọn wọ̀nyí ni wọ́n yàn nínú àwùjọ ènìyàn, olórí àwọn ẹ̀yà baba wọn. Àwọn ni olórí àwọn ẹbí Israẹli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.