Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Juda, Benjamini, Ṣemaiah, Jeremiah,

Nehemiah 12:34 in English

Nehemiah 12:34 · Berean Standard Bible

Judah, Benjamin, Shemaiah, Jeremiah,

Context

32Hoṣaiah àti ìdajì àwọn olórí Juda tẹ̀lé wọn, 33àwọn wọ̀nyí náà sì lọ pẹ̀lú wọn, Asariah, Esra, Meṣullamu, 34Juda, Benjamini, Ṣemaiah, Jeremiah, 35pẹ̀lú àwọn àlùfáà díẹ̀ pẹ̀lú ìpè, pẹ̀lú u Sekariah ọmọ Jonatani, ọmọ Ṣemaiah, ọmọ Mattaniah, ọmọ Mikaiah, ọmọ Sakkuri, ọmọ Asafu, 36àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, Ṣemaiah, Asareeli, Milalai, Gilalai, Maai, Netaneli, Juda àti Hanani—pẹ̀lú ohun èlò orin bí àṣẹ Dafidi ènìyàn Ọlọ́run. Esra akọ̀wé ni ó ṣáájú wọn bí wọ́n ti ń tò lọ lọ́wọ̀ọ̀wọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.