Nehemiah 11:32
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní Anatoti, Nobu àti Ananiah,
Nehemiah 11:32 in English
Nehemiah 11:32 · Berean Standard Bible
in Anathoth, Nob, Ananiah,
Context
30Sanoa, Adullamu àti àwọn ìletò o wọn, ní Lakiṣi àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Aseka àti àwọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Beerṣeba títí dé àfonífojì Hinnomu. 31Àwọn ọmọ Benjamini láti Geba ń gbé ní Mikmasi, Aija, Beteli àti àwọn ìletò rẹ̀. 32Ní Anatoti, Nobu àti Ananiah, 33ní Hasori Rama àti Gittaimu, 34ní Hadidi, Seboimu àti Neballati,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.