Native Bible

Matthew 22:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó wí pé, “Olùkọ́ èwo ni ó ga jùlọ nínú àwọn òfin?”

Matthew 22:36 in English

Matthew 22:36 · Berean Standard Bible

“Teacher, which commandment is the greatest in the Law?”

Context

34Nígbà ti wọ́n sì gbọ́ pé ó ti pa àwọn Sadusi lẹ́nu mọ́, àwọn Farisi pé ara wọn jọ. 35Ọ̀kan nínú wọn tí ṣe amòfin dán an wò pẹ̀lú ìbéèrè yìí. 36Ó wí pé, “Olùkọ́ èwo ni ó ga jùlọ nínú àwọn òfin?” 37Jesu dáhùn pé, “ ‘Fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo inú rẹ.’ 38Èyí ni òfin àkọ́kọ́ àti èyí tí ó tóbi jùlọ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.