Matiu 15:39
Matthew 15:39 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Lẹ́yìn náà, Jesu rán àwọn ènìyàn náà lọ sí ilé wọn, ó sì bọ́ sínú ọkọ̀, ó rékọjá lọ sí ẹkùn Magadani.
Matthew 15:39 in English
Matthew 15:39 · Berean Standard Bible
After Jesus had dismissed the crowds, He got into the boat and went to the region of Magadan.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.