Matiu 14:1
Matthew 14:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní àkókò náà ni Herodu ọba tetrarki gbọ́ nípa òkìkí Jesu,
Matthew 14:1 in English
Matthew 14:1 · Berean Standard Bible
At that time Herod the tetrarch heard the reports about Jesus
Context
1Ní àkókò náà ni Herodu ọba tetrarki gbọ́ nípa òkìkí Jesu, 2ó wí fún àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé, “Dájúdájú Johanu onítẹ̀bọmi ni èyí, ó jíǹde kúrò nínú òkú. Ìdí nìyí tí ó fi ní agbára láti ṣiṣẹ́ ìyanu wọ̀nyí.” 3Nísinsin yìí Herodu ti mú Johanu, ó fi ẹ̀wọ̀n dè é, ó sì fi sínú túbú, nítorí Herodia aya Filipi arákùnrin rẹ̀,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.