Native Bible

Matthew 13:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ní ọjọ́ kan náà, Jesu kúrò ní ilé, ó jókòó sí etí Òkun.

Matthew 13:1 in English

Matthew 13:1 · Berean Standard Bible

That same day Jesus went out of the house and sat by the sea.

Context

1Ní ọjọ́ kan náà, Jesu kúrò ní ilé, ó jókòó sí etí Òkun. 2Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn péjọ sọ́dọ̀ rẹ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi bọ́ sínú ọkọ̀ ojú omi, ó jókòó, gbogbo ènìyàn sì dúró létí Òkun. 3Nígbà náà ni ó fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe bá wọn sọ̀rọ̀, wí pé, “Àgbẹ̀ kan jáde lọ gbin irúgbìn sínú oko rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.