Native Bible

Leviticus 25:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sọ fún Mose ní orí òkè Sinai pé,

Leviticus 25:1 in English

Leviticus 25:1 · Berean Standard Bible

Then the LORD said to Moses on Mount Sinai,

Context

1Olúwa sọ fún Mose ní orí òkè Sinai pé, 2“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli, kí o sì wí fún wọn pé, ‘Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ náà tí èmi ó fi fún yín, ilẹ̀ náà gbọdọ̀ sinmi fún Olúwa. 3Ọdún mẹ́fà ni ìwọ ó fi gbin oko rẹ, ọdún mẹ́fà ni ìwọ ó fi tọ́jú ọgbà àjàrà rẹ, tí ìwọ ó sì fi kó èso wọn jọ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.