Ẹkún Jeremiah 3:36
Lamentations 3:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
láti yí ìdájọ́ ènìyàn padà, ǹjẹ́ Olúwa kò rí ohun bẹ́ẹ̀.
Lamentations 3:36 in English
Lamentations 3:36 · Berean Standard Bible
to subvert a man in his lawsuit— of these the Lord does not approve.
Context
34Láti tẹ mọ́lẹ̀ lábẹ́ ẹsẹ̀
gbogbo àwọn ẹlẹ́wọ̀n ní ilẹ̀ náà. 35Láti ṣẹ́ ọmọ ènìyàn fún ẹ̀tọ́ rẹ̀
níwájú Ọ̀gá-ògo jùlọ, 36láti yí ìdájọ́ ènìyàn padà,
ǹjẹ́ Olúwa kò rí ohun bẹ́ẹ̀. 37Ta ni yóò sọ̀rọ̀ tí yóò rí bẹ́ẹ̀
tí Olúwa kò bá fi àṣẹ sí i. 38Ǹjẹ́ kì í ṣe láti ẹnu Ọ̀gá-ògo jùlọ
ni rere àti búburú tí ń wá?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.