Joṣua 21:28
Joshua 21:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Láti ara ẹ̀yà Isakari ni wọ́n ti fún wọn ní, Kiṣioni Daberati,
Joshua 21:28 in English
Joshua 21:28 · Berean Standard Bible
From the tribe of Issachar they were given Kishion, Daberath,
Context
26Gbogbo ìlú mẹ́wẹ̀ẹ̀wá yìí àti ilẹ̀ pápá wọn ni a fi fún ìyókù ìdílé Kohati. 27Àwọn ọmọ Gerṣoni ìdílé àwọn ọmọ Lefi ni wọ́n fún lára:
ìdajì ẹ̀yà Manase,
Golani ní Baṣani (ìlú ààbò fún apànìyàn) àti Be-Eṣterah pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọ́n jẹ́ méjì. 28Láti ara ẹ̀yà Isakari ni wọ́n ti fún wọn ní,
Kiṣioni Daberati, 29Jarmatu àti Eni-Gannimu, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin. 30Láti ara ẹ̀yà Aṣeri ni wọ́n ti fún wọn ní
Miṣali, àti Abdoni,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.