Native Bible

Joshua 18:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Beti-Araba, Semaraimu, Beteli,

Joshua 18:22 in English

Joshua 18:22 · Berean Standard Bible

Beth-arabah, Zemaraim, Bethel,

Context

20Odò Jordani sí jẹ́ ààlà ní ìhà ìlà-oòrùn. Ìwọ̀nyí ní àwọn ààlà ti ó sàmì sí ìní àwọn ìdílé Benjamini ní gbogbo àwọn àyíká wọn. 21Ẹ̀yà Benjamini ní agbo ilé, agbo ilé ni àwọn ìlú wọ̀nyí: Jeriko, Beti-Hogla, Emeki-Keṣiṣi, 22Beti-Araba, Semaraimu, Beteli, 23Affimu, Para, Ofira 24Kefari, Ammoni, Ofini àti Geba; àwọn ìlú méjìlá àti ìletò wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.