Native Bible

Job 42:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà náà ní Jobu dá Olúwa lóhùn, ó sì wí pé,

Job 42:1 in English

Job 42:1 · Berean Standard Bible

Then Job replied to the LORD:

Context

1Nígbà náà ní Jobu dá Olúwa lóhùn, ó sì wí pé, 2“Èmi mọ̀ pé, ìwọ lè e ṣe ohun gbogbo, àti pé, kò si ìrò inú tí a lè fa sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ rẹ. 3Ìwọ béèrè, ta ni ẹni tí ń fi ìgbìmọ̀ pamọ́ láìní ìmọ̀? Nítorí náà ní èmi ṣe ń sọ èyí tí èmi kò mọ̀, ohun tí ó ṣe ìyanu jọjọ níwájú mi, ti èmi kò mòye.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.