Jobu 4:13
Job 4:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní ìrò inú lójú ìran òru, nígbà tí oorun èjìká kùn ènìyàn.
Job 4:13 in English
Job 4:13 · Berean Standard Bible
In disquieting visions in the night, when deep sleep falls on men,
Context
11Kìnnìún kígbe, nítorí àìrí ohun ọdẹ,
àwọn ẹgbọrọ kìnnìún sísanra ni a túká kiri. 12“Ǹjẹ́ nísinsin yìí a fi ohun àṣírí kan hàn fún mi,
etí mi sì gbà díẹ̀ nínú rẹ̀. 13Ní ìrò inú lójú ìran òru,
nígbà tí oorun èjìká kùn ènìyàn. 14Ẹ̀rù bà mí àti ìwárìrì
tí ó mú gbogbo egungun mi jí pépé. 15Nígbà náà ni ẹ̀mí kan kọjá lọ ní iwájú mi,
irun ara mi dìde dúró ṣánṣán.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.