Native Bible

Job 4:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ̀rù bà mí àti ìwárìrì tí ó mú gbogbo egungun mi jí pépé.

Job 4:14 in English

Job 4:14 · Berean Standard Bible

fear and trembling came over me and made all my bones shudder.

Context

12“Ǹjẹ́ nísinsin yìí a fi ohun àṣírí kan hàn fún mi, etí mi sì gbà díẹ̀ nínú rẹ̀. 13Ní ìrò inú lójú ìran òru, nígbà tí oorun èjìká kùn ènìyàn. 14Ẹ̀rù bà mí àti ìwárìrì tí ó mú gbogbo egungun mi jí pépé. 15Nígbà náà ni ẹ̀mí kan kọjá lọ ní iwájú mi, irun ara mi dìde dúró ṣánṣán. 16Ó dúró jẹ́ẹ́, ṣùgbọ́n èmi kò le wo àpẹẹrẹ ìrí rẹ̀, àwòrán kan hàn níwájú mi, ìdákẹ́rọ́rọ́ wà, mo sì gbóhùn kan wí pé,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.