Jobu 39:27
Job 39:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Idì ha máa fi àṣẹ rẹ̀ fò sókè, kí ó sì lọ tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí òkè gíga?
Job 39:27 in English
Job 39:27 · Berean Standard Bible
Does the eagle soar at your command and make his nest on high?
Context
25Ó wí nígbà ìpè pé, Háà! Háà!
Ó sì gbóhùn ogun lókèèrè réré,
igbe àwọn balógun àti ìhó ayọ̀ ogun wọn. 26“Àwòdì ha máa ti ipa ọgbọ́n rẹ̀ fò sókè,
tí ó sì na ìyẹ́ apá rẹ̀ sí ìhà gúúsù? 27Idì ha máa fi àṣẹ rẹ̀ fò sókè,
kí ó sì lọ tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí òkè gíga? 28Ó ń gbé, ó sì ń wò ní orí àpáta,
lórí pàlàpálá òkúta àti ibi orí òkè. 29Láti ibẹ̀ lọ ni ó ti ń wá oúnjẹ kiri,
ojú rẹ̀ sì ríran rí òkè réré.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.