Jobu 36:20
Job 36:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Má ṣe ìfẹ́ òru, nígbà tí a ń ké àwọn orílẹ̀-èdè kúrò ní ipò wọn.
Job 36:20 in English
Job 36:20 · Berean Standard Bible
Do not long for the night, when people vanish from their homes.
Context
18Nítorí ìbínú ń bẹ, ṣọ́ra kí òtítọ́ rẹ máa bá a tàn ọ;
láti jẹ́ kí títóbi rẹ mú ọ ṣìnà. 19Ọrọ̀ rẹ pọ̀ tó, tí wàhálà kì yóò fi dé bá ọ bí?
Tàbí ipa agbára rẹ? 20Má ṣe ìfẹ́ òru, nígbà tí a ń ké
àwọn orílẹ̀-èdè kúrò ní ipò wọn. 21Máa ṣọ́ra kí ìwọ ki ó má yí ara rẹ̀ padà sí búburú,
nítorí èyí tí ìwọ rò pé ó dára jù ìpọ́njú lọ. 22“Kíyèsi i, Ọlọ́run ni gbéga nípa agbára rẹ̀;
ta ni jẹ́ olùkọ́ni bí rẹ̀?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.