Jobu 34:24
Job 34:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òun ó sì fọ́ àwọn alágbára túútúú láìní ìwádìí, a sì fi ẹlòmíràn dípò wọn,
Job 34:24 in English
Job 34:24 · Berean Standard Bible
He shatters the mighty without inquiry and sets up others in their place.
Context
22Kò sí ibi òkùnkùn, tàbí òjìji ikú,
níbi tí àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ yóò gbé sá pamọ́ sí. 23Nítorí pé òun kò pẹ́ àti kíyèsi ẹnìkan,
kí òun kí ó sì mú lọ sínú ìdájọ́ níwájú Ọlọ́run. 24Òun ó sì fọ́ àwọn alágbára túútúú láìní ìwádìí,
a sì fi ẹlòmíràn dípò wọn, 25nítorí pé ó mọ iṣẹ́ wọn,
ó sì yí wọn po ní òru, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n di ìtẹ̀mọ́lẹ̀. 26Ó kọlù wọ́n nítorí ìwà búburú wọn
níbi tí àwọn ẹlòmíràn ti lè rí i,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.