Jobu 34:16
Job 34:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ǹjẹ́ nísinsin yìí, bí ìwọ bá ní òye, gbọ́ èyí; fetísí ohùn ẹnu mi.
Job 34:16 in English
Job 34:16 · Berean Standard Bible
If you have understanding, hear this; listen to my words.
Context
14Bí ó bá gbé ayé rẹ̀ lé kìkì ara rẹ̀
tí ó sì gba ọkàn rẹ̀ àti ẹ̀mí rẹ̀ sọ́dọ̀ ara rẹ̀, 15gbogbo ènìyàn ni yóò parun pọ̀,
ènìyàn a sì tún padà di erùpẹ̀. 16“Ǹjẹ́ nísinsin yìí, bí ìwọ bá ní òye,
gbọ́ èyí; fetísí ohùn ẹnu mi. 17Ẹni tí ó kórìíra òtítọ́ ha le ṣe olórí bí?
Ìwọ ó ha sì dá olóòótọ́ àti ẹni ńlá lẹ́bi? 18O ha tọ́ láti wí fún ọba pé, ‘Ènìyàn búburú ní ìwọ,’
tàbí fún àwọn ọmọ-aládé pé, ‘Ìkà ni ẹ̀yin,’
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.