Jobu 33:3
Job 33:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi, ètè mi yóò sì sọ ìmọ̀ mi jáde dájúdájú.
Job 33:3 in English
Job 33:3 · Berean Standard Bible
My words are from an upright heart, and my lips speak sincerely what I know.
Context
1“Ǹjẹ́ nítorí náà, Jobu, èmí bẹ̀ ọ,
gbọ́ ọ̀rọ̀ mi kí o sì fetísí ọ̀rọ̀ mi! 2Kíyèsi i nísinsin yìí, èmí ya ẹnu mi,
ahọ́n mi sì sọ̀rọ̀ ní ẹnu mi. 3Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi,
ètè mi yóò sì sọ ìmọ̀ mi jáde dájúdájú. 4Ẹ̀mí Ọlọ́run ni ó tí dá mi,
àti ìmísí Olódùmarè ni ó ti fún mi ní ìyè. 5Bí ìwọ bá le dá mi lóhùn,
tò ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ níwájú mi;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.