Jobu 33:29
Job 33:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́run máa ń ṣe fún ènìyàn nígbà méjì àti nígbà mẹ́ta,
Job 33:29 in English
Job 33:29 · Berean Standard Bible
Behold, all these things God does to a man, two or even three times,
Context
27Ó wá sọ́dọ̀ ènìyàn ó sì wí pé,
‘Èmi ṣẹ̀, kò sì ṣí èyí tí o tọ́, mo sì ti yí èyí tí ó tọ́ po,
a kò sì san ẹ̀san rẹ̀ fún mi; 28Ọlọ́run ti gba ọkàn mi kúrò nínú lílọ sínú ihò,
ẹ̀mí mi yóò wà láti jẹ adùn ìmọ́lẹ̀ ayé.’ 29“Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́run
máa ń ṣe fún ènìyàn nígbà méjì àti nígbà mẹ́ta, 30láti mú ọkàn rẹ padà kúrò nínú isà òkú,
láti fi ìmọ́lẹ̀ alààyè han sí i. 31“Jobu, kíyèsi i gidigidi, kí o sì fetí sí mi;
pa ẹnu rẹ mọ́, èmi ó sì máa sọ ọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.