Jobu 33:15
Job 33:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nínú àlá, ní ojúran òru, nígbà tí orun èjìká bá kùn ènìyàn lọ, ní sísùn lórí ibùsùn,
Job 33:15 in English
Job 33:15 · Berean Standard Bible
In a dream, in a vision in the night, when deep sleep falls upon men as they slumber on their beds,
Context
13Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé,
òun kò ní sọ ọ̀rọ̀ kan nítorí iṣẹ́ rẹ̀? 14Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan,
àní, lẹ́ẹ̀kejì, ṣùgbọ́n ènìyàn kò róye rẹ̀. 15Nínú àlá, ní ojúran òru,
nígbà tí orun èjìká bá kùn ènìyàn lọ,
ní sísùn lórí ibùsùn, 16nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn,
yóò sì dẹ́rùbà wọ́n pẹ̀lú ìbáwí, 17kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀;
kí ó sì pa ìgbéraga mọ́ kúrò lọ́dọ̀ ènìyàn;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.