Jobu 31:37
Job 31:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi ìbá sì sọ iye ìṣísẹ̀ mi fún un, bí ọmọ-aládé ni èmi ìbá súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ̀.)
Job 31:37 in English
Job 31:37 · Berean Standard Bible
I would give account of all my steps; I would approach Him like a prince.)—
Context
35(“Ìbá ṣe pé ẹnìkan le gbọ́ ti èmí!
Kíyèsi i, àmì mi, kí Olódùmarè kí ó dá mi lóhùn,
kí èmí kí ó sì rí ìwé náà tí olùfisùn mi ti kọ. 36Nítòótọ́ èmí ìbá gbé le èjìká mi,
èmi ìbá sì dé bí adé mọ́ orí mi. 37Èmi ìbá sì sọ iye ìṣísẹ̀ mi fún un,
bí ọmọ-aládé ni èmi ìbá súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ̀.) 38“Bí ilẹ̀ mi bá sì ké rara lòdì sí mi
tí a sì fi omijé kún gbogbo poro rẹ̀. 39Bí mo bá jẹ èso oko mi láìsan owó
tàbí tí mo sì mú ọkàn olúwa rẹ̀ fò lọ,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.