Jobu 31:30
Job 31:30 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bẹ́ẹ̀ èmi kò sì jẹ ki ẹnu mi ki ó ṣẹ̀ nípa fífẹ́ ègún sí ọkàn rẹ̀.
Job 31:30 in English
Job 31:30 · Berean Standard Bible
I have not allowed my mouth to sin by asking for his life with a curse—
Context
28èyí pẹ̀lú ni ẹ̀ṣẹ̀ ti àwọn onídàájọ́ ní láti bẹ̀wò,
nítorí pé èmí yóò jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run tí ó wà lókè. 29“Bí ó bá ṣe pé mo yọ̀ sì ìparun ẹni tí ó kórìíra mi.
Tàbí bí mo bá sì gbéraga sókè, nígbà tí ibi bá a. 30Bẹ́ẹ̀ èmi kò sì jẹ ki ẹnu mi ki ó ṣẹ̀
nípa fífẹ́ ègún sí ọkàn rẹ̀. 31Bí àwọn ènìyàn inú àgọ́ mi kò bá lè wí pé,
‘Ta ni kò ì tí ì jẹ ẹran rẹ̀ ní àjẹyó?’ 32Àlejò kò wọ̀ ni ìgboro rí;
èmí ṣí ìlẹ̀kùn mi sílẹ̀ fún èrò.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.