Jobu 31:27
Job 31:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
bí a bá tàn ọkàn mi jẹ láti fi ẹnu mi kò ọwọ́ mi,
Job 31:27 in English
Job 31:27 · Berean Standard Bible
so that my heart was secretly enticed and my hand threw a kiss from my mouth,
Context
25bí mo bá yọ̀ nítorí ọrọ̀ mí pọ̀,
àti nítorí ọwọ́ mi dara lọ́pọ̀lọ́pọ̀, 26bí mo bá bojú wo oòrùn nígbà tí ń ràn,
tàbí òṣùpá tí ń ràn nínú ìtànmọ́lẹ̀, 27bí a bá tàn ọkàn mi jẹ
láti fi ẹnu mi kò ọwọ́ mi, 28èyí pẹ̀lú ni ẹ̀ṣẹ̀ ti àwọn onídàájọ́ ní láti bẹ̀wò,
nítorí pé èmí yóò jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run tí ó wà lókè. 29“Bí ó bá ṣe pé mo yọ̀ sì ìparun ẹni tí ó kórìíra mi.
Tàbí bí mo bá sì gbéraga sókè, nígbà tí ibi bá a.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.