Jobu 31:25
Job 31:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
bí mo bá yọ̀ nítorí ọrọ̀ mí pọ̀, àti nítorí ọwọ́ mi dara lọ́pọ̀lọ́pọ̀,
Job 31:25 in English
Job 31:25 · Berean Standard Bible
if I have rejoiced in my great wealth because my hand had gained so much,
Context
23Nítorí pé ìparun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá ni ẹ̀rù ńlá fún mi,
àti nítorí ọláńlá rẹ̀ èmi kò le è dúró. 24“Bí ó bá ṣe pé mo fi wúrà ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé mi,
tàbí tí mo bá wí fún fàdákà dídára pé, ‘Ìwọ ni ààbò mi,’ 25bí mo bá yọ̀ nítorí ọrọ̀ mí pọ̀,
àti nítorí ọwọ́ mi dara lọ́pọ̀lọ́pọ̀, 26bí mo bá bojú wo oòrùn nígbà tí ń ràn,
tàbí òṣùpá tí ń ràn nínú ìtànmọ́lẹ̀, 27bí a bá tàn ọkàn mi jẹ
láti fi ẹnu mi kò ọwọ́ mi,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.