Jobu 3:25
Job 3:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé ohun náà tí mo bẹ̀rù gidigidi ni ó dé bá mi yìí, àti ohun tí mo fòyà rẹ̀ bá mi ó sì ṣubú lù mí.
Job 3:25 in English
Job 3:25 · Berean Standard Bible
For the thing I feared has overtaken me, and what I dreaded has befallen me.
Context
23Kí ni a fi ìmọ́lẹ̀ fún ẹni
tí ọ̀nà rẹ̀ fi ara pamọ́ fún,
tí Ọlọ́run sì ṣọgbà dí mọ́ ká? 24Nítorí pé èémí-ẹ̀dùn wà ṣáájú oúnjẹ mi;
ìkérora mi sì tú jáde bí omi. 25Nítorí pé ohun náà tí mo bẹ̀rù gidigidi ni ó dé bá mi yìí,
àti ohun tí mo fòyà rẹ̀ bá mi ó sì ṣubú lù mí. 26Èmi wà láìní àlàáfíà, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ní ìsinmi;
bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ni ìfàyàbalẹ̀, bí kò ṣe ìdààmú.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.