Jobu 28:27
Job 28:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nígbà náà ni ó rí i, ó sì sọ ọ́ jáde; ó pèsè rẹ̀ sílẹ̀, ó sì ṣe ìwádìí rẹ̀ rí.
Job 28:27 in English
Job 28:27 · Berean Standard Bible
then He looked at wisdom and appraised it; He established it and searched it out.
Context
25láti dà òsùwọ̀n fún afẹ́fẹ́,
ó sì fi òsùwọ̀n wọ́n omi. 26Nígbà tí ó pàṣẹ fún òjò,
tí ó sì la ọ̀nà fún mọ̀nàmọ́ná àrá, 27nígbà náà ni ó rí i, ó sì sọ ọ́ jáde;
ó pèsè rẹ̀ sílẹ̀, ó sì ṣe ìwádìí rẹ̀ rí. 28Àti fún ènìyàn ni ó wí pé,
“Kíyèsi i, ẹ̀rù Olúwa èyí ni ọgbọ́n,
àti láti jáde kúrò nínú ìwà búburú èyí ni òye.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.