Native Bible

Job 20:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Nítorí náà ní ìrò inú mi dá mi lóhùn, àti nítorí èyí náà ní mo sì yára si gidigidi.

Job 20:2 in English

Job 20:2 · Berean Standard Bible

“So my anxious thoughts compel me to answer, because of the turmoil within me.

Context

1Ìgbà náà ní Sofari, ará Naama dáhùn, ó sì wí pé, 2“Nítorí náà ní ìrò inú mi dá mi lóhùn, àti nítorí èyí náà ní mo sì yára si gidigidi. 3Mo ti gbọ́ ẹ̀san ẹ̀gàn mi, ẹ̀mí òye mi sì dá mi lóhùn. 4“Ìwọ kò mọ̀ èyí rí ní ìgbà àtijọ́, láti ìgbà tí a sọ ènìyàn lọ́jọ̀ sílé ayé,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.