Jobu 19:9
Job 19:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó ti bọ́ ògo mi, ó sì ṣí adé kúrò ní orí mi.
Job 19:9 in English
Job 19:9 · Berean Standard Bible
He has stripped me of my honor and removed the crown from my head.
Context
7“Kíyèsi, èmi ń kígbe pe, ‘Ọwọ́ alágbára!’ Ṣùgbọ́n a kò gbọ́ ti èmi;
mo kígbe fún ìrànlọ́wọ́, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ìdájọ́. 8Ó ṣọgbà dí ọ̀nà mi tí èmi kò le è kọjá,
Ó sì mú òkùnkùn ṣú sí ipa ọ̀nà mi. 9Ó ti bọ́ ògo mi,
ó sì ṣí adé kúrò ní orí mi. 10Ó ti bà mí jẹ́ ní ìhà gbogbo,
ẹ̀mí sì pin; ìrètí mi ni a ó sì fàtu bí igi. 11Ó sì tiná bọ ìbínú rẹ̀ sí mi,
ó sì kà mí sí bí ọ̀kan nínú àwọn ọ̀tá rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.