Jobu 15:8
Job 15:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ gbúròó àṣírí Ọlọ́run rí? Tàbí ìwọ ha dá ọgbọ́n dúró sọ́dọ̀ ara rẹ?
Job 15:8 in English
Job 15:8 · Berean Standard Bible
Do you listen in on the council of God or limit wisdom to yourself?
Context
6Ẹnu ara rẹ̀ ni ó dá lẹ́bi, kì í ṣe èmi;
àní ètè ara rẹ̀ ni ó jẹ́rìí gbè ọ́. 7“Ìwọ ha í ṣe ọkùnrin tí a kọ́ bí?
Tàbí a ha dá ọ ṣáájú àwọn òkè? 8Ìwọ gbúròó àṣírí Ọlọ́run rí?
Tàbí ìwọ ha dá ọgbọ́n dúró sọ́dọ̀ ara rẹ? 9Kí ni ìwọ mọ̀ tí àwa kò mọ̀?
Òye kí ní ó yé ọ tí kò sí nínú wa? 10Àwọn arúgbó àti ògbólógbòó ènìyàn wà pẹ̀lú wa,
tí wọ́n dàgbà ju baba rẹ lọ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.