Jobu 12:24
Job 12:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òun a gba òye àwọn olórí àwọn ènìyàn aráyé, a sì máa mú wọn rin kiri nínú ijù níbi tí ọ̀nà kò sí.
Job 12:24 in English
Job 12:24 · Berean Standard Bible
He deprives the earth’s leaders of reason and makes them wander in a trackless wasteland.
Context
22Ó hú ìdí ohun ìjìnlẹ̀ jáde láti inú òkùnkùn wá
ó sì mú òjìji ikú wá sínú ìmọ́lẹ̀. 23Òun a mú orílẹ̀-èdè bí sí i, a sì run wọ́n;
òun a sọ orílẹ̀-èdè di ńlá, a sì tún ṣẹ̀ wọn kù. 24Òun a gba òye àwọn olórí àwọn ènìyàn aráyé,
a sì máa mú wọn rin kiri nínú ijù níbi tí ọ̀nà kò sí. 25Wọn a máa fi ọwọ́ ta ilẹ̀ nínú òkùnkùn níbi tí kò sí ìmọ́lẹ̀;
òun a sì máa mú ìrìn ìsìn wọn bí ọ̀mùtí.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.