Jobu 12:11
Job 12:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Etí kì í dán ọ̀rọ̀ wò bí tàbí adùn ẹnu kì í sì í tọ́ oúnjẹ rẹ̀ wò bí?
Job 12:11 in English
Job 12:11 · Berean Standard Bible
Does not the ear test words as the tongue tastes its food?
Context
9Ta ni kò mọ̀ nínú gbogbo nǹkan wọ̀nyí pé,
ọwọ́ Olúwa ni ó ṣe nǹkan yìí? 10Ní ọwọ́ ẹni tí ẹ̀mí ohun alààyè gbogbo gbé wà,
àti ẹ̀mí gbogbo aráyé. 11Etí kì í dán ọ̀rọ̀ wò bí
tàbí adùn ẹnu kì í sì í tọ́ oúnjẹ rẹ̀ wò bí? 12Àwọn arúgbó ni ọgbọ́n wà fún,
àti nínú gígùn ọjọ́ ni òye. 13“Ti Ọlọ́run ni ọgbọ́n àti agbára;
òun ló ni ìmọ̀ àti òye.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.