Native Bible

Job 12:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jobu sì dáhùn, ó sì wí pé,

Job 12:1 in English

Context

1Jobu sì dáhùn, ó sì wí pé, 2“Kò sí àní àní níbẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ni àwọn ènìyàn náà, ọgbọ́n yóò sì kú pẹ̀lú yín! 3Ṣùgbọ́n èmi ní ìyè nínú gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin; èmi kò kéré sí i yín. Àní, ta ni kò mọ gbogbo nǹkan wọ̀nyí?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.