Jobu 10:19
Job 10:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Tí kò bá le jẹ́ pé èmi wà láààyè, à bá ti gbé mi láti inú lọ isà òkú.
Job 10:19 in English
Job 10:19 · Berean Standard Bible
If only I had never come to be, but had been carried from the womb to the grave.
Context
17Ìwọ sì tún mu àwọn ẹlẹ́rìí rẹ dìde sí mi di ọ̀tún
ìwọ sì sọ ìrunú rẹ di púpọ̀ sí mi;
àwọn ogun rẹ si dìde sinmi bi igbe omi Òkun. 18“Nítorí kí ni ìwọ ṣe mú mi jáde láti inú wá?
Háà! Èmi ìbá kúkú ti kú, ojúkójú kì bá tí rí mi. 19Tí kò bá le jẹ́ pé èmi wà láààyè,
à bá ti gbé mi láti inú lọ isà òkú. 20Ọjọ́ mi kò ha kúrú bí? Rárá!
Dáwọ́ dúró, kí ó sì yí padà kúrò lọ́dọ̀ mi.
Nítorí kí èmi lè ni ayọ̀ ní ìṣẹ́jú kan. 21Kí èmi kí ó tó lọ sí ibi tí èmi kì yóò padà sẹ́yìn mọ́,
àní si ilẹ̀ òkùnkùn àti òjìji ikú,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.