Jobu 10:18
Job 10:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Nítorí kí ni ìwọ ṣe mú mi jáde láti inú wá? Háà! Èmi ìbá kúkú ti kú, ojúkójú kì bá tí rí mi.
Job 10:18 in English
Job 10:18 · Berean Standard Bible
Why then did You bring me from the womb? Oh, that I had died, and no eye had seen me!
Context
16Bí mo bá gbé orí mi ga, ìwọ ń dẹ mí kiri bi i kìnnìún
àti pẹ̀lú, ìwọ a sì fi ara rẹ hàn fún mi ní ìyànjú. 17Ìwọ sì tún mu àwọn ẹlẹ́rìí rẹ dìde sí mi di ọ̀tún
ìwọ sì sọ ìrunú rẹ di púpọ̀ sí mi;
àwọn ogun rẹ si dìde sinmi bi igbe omi Òkun. 18“Nítorí kí ni ìwọ ṣe mú mi jáde láti inú wá?
Háà! Èmi ìbá kúkú ti kú, ojúkójú kì bá tí rí mi. 19Tí kò bá le jẹ́ pé èmi wà láààyè,
à bá ti gbé mi láti inú lọ isà òkú. 20Ọjọ́ mi kò ha kúrú bí? Rárá!
Dáwọ́ dúró, kí ó sì yí padà kúrò lọ́dọ̀ mi.
Nítorí kí èmi lè ni ayọ̀ ní ìṣẹ́jú kan.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.