Native Bible

John 8:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jesu sì lọ sí orí òkè olifi.

John 8:1 in English

John 8:1 · Berean Standard Bible

But Jesus went to the Mount of Olives.

Context

1Jesu sì lọ sí orí òkè olifi. 2Ó sì tún padà wá sí tẹmpili ní kùtùkùtù òwúrọ̀, gbogbo ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀; ó sì jókòó, ó ń kọ́ wọn. 3Àwọn akọ̀wé àti àwọn Farisi sì mú obìnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ̀, tí a mú nínú ṣíṣe panṣágà; wọ́n sì mú un dúró láàrín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.