Native Bible

John 7:53 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n sì lọ olúkúlùkù sí ilé rẹ̀.

John 7:53 in English

John 7:53 · Berean Standard Bible

Then each went to his own home.

Context

51“Òfin wa ha ń ṣe ìdájọ́ ènìyàn kí ó tó gbọ́ ti ẹnu rẹ̀ àti kí ó tó mọ ohun tí ó ṣe bí?” 52Wọ́n dáhùn wọ́n sì wí fún un pé, “Ìwọ pẹ̀lú wá láti Galili bí? Wá kiri, kí o sì wò nítorí kò sí wòlíì kan tí ó ti Galili dìde.” 53Wọ́n sì lọ olúkúlùkù sí ilé rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.