Native Bible

John 4:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó fi Judea sílẹ̀, ó sì tún lọ sí Galili.

John 4:3 in English

John 4:3 · Berean Standard Bible

He left Judea and returned to Galilee.

Context

1Àwọn Farisi sì gbọ́ pé, Jesu ni, ó sì ń ṣe ìtẹ̀bọmi fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn púpọ̀ ju Johanu lọ. 2Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Jesu tìkára rẹ̀ kò ṣe ìtẹ̀bọmi bí kò ṣe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, 3Ó fi Judea sílẹ̀, ó sì tún lọ sí Galili. 4Òun sì ní láti kọjá láàrín Samaria. 5Nígbà náà ni ó dé ìlú Samaria kan, tí a ń pè ní Sikari, tí ó súnmọ́ etí ilẹ̀ oko tí Jakọbu ti fi fún Josẹfu, ọmọ rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.