Native Bible

John 19:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí náà ni Pilatu mú Jesu, ó sì nà án.

John 19:1 in English

John 19:1 · Berean Standard Bible

Then Pilate took Jesus and had Him flogged.

Context

1Nítorí náà ni Pilatu mú Jesu, ó sì nà án. 2Àwọn ọmọ-ogun sì hun adé ẹ̀gún, wọ́n sì fi dé e ní orí, wọ́n sì fi aṣọ ìgúnwà elése àlùkò wọ̀ ọ́. 3Wọ́n sì wí pé, “Kábíyèsí, ọba àwọn Júù!” Wọ́n sì fi ọwọ́ wọn gbá a ní ojú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.