Native Bible

John 10:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ sì gbà á gbọ́.

John 10:42 in English

John 10:42 · Berean Standard Bible

And many in that place believed in Jesus.

Context

40Ó sì tún kọjá lọ sí apá kejì Jordani sí ibi tí Johanu ti kọ́kọ́ ń bamitiisi; níbẹ̀ ni ó sì jókòó. 41Àwọn ènìyàn púpọ̀ sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì wí pé, “Johanu kò ṣe iṣẹ́ àmì kan, Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni ohun gbogbo tí Johanu sọ nípa ti ọkùnrin yìí.” 42Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ sì gbà á gbọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.