Jeremiah 51:1
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ohùn ti Olúwa wí nìyìí: “Wò ó èmi yóò ru afẹ́fẹ́ apanirun sókè sí Babeli àti àwọn ènìyàn Lebikamai,
Jeremiah 51:1 in English
Jeremiah 51:1 · Berean Standard Bible
This is what the LORD says: “Behold, I will stir up against Babylon and against the people of Leb-kamai * the spirit of a destroyer.
Context
1Ohùn ti Olúwa wí nìyìí:
“Wò ó èmi yóò ru afẹ́fẹ́ apanirun sókè
sí Babeli àti àwọn ènìyàn Lebikamai, 2Èmi yóò rán àwọn àjèjì ènìyàn sí Babeli
láti fẹ́ ẹ, tí yóò sì sọ ilẹ̀ rẹ̀ di òfo;
wọn yóò takò ó ní gbogbo ọ̀nà
ní ọjọ́ ìparun rẹ̀. 3Má ṣe jẹ́ kí tafàtafà yọ ọfà rẹ̀,
jáde tàbí kí ó di ìhámọ́ra rẹ̀.
Má ṣe dá àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sí;
pátápátá ni kí o pa àwọn ọmọ-ogun rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.