Jeremiah 5:30
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Nǹkan ìbànújẹ́ àti ohun ìtara ti ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ náà.
Jeremiah 5:30 in English
Jeremiah 5:30 · Berean Standard Bible
A horrible and shocking thing has happened in the land.
Context
28wọ́n sanra wọ́n sì ń dán.
Ìwà búburú wọn kò sì lópin;
wọn kò bẹ̀bẹ̀ fún ẹjọ́ àwọn aláìní baba láti borí rẹ̀.
Wọn kò jà fún ẹ̀tọ́ àwọn tálákà. 29Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n fún èyí bí?”
ni Olúwa wí.
“Èmi kì yóò wá gbẹ̀san ara mi
lára orílẹ̀-èdè bí èyí bí? 30“Nǹkan ìbànújẹ́ àti ohun ìtara
ti ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ náà. 31Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké,
àwọn àlùfáà sì ń ṣe àkóso pẹ̀lú àṣẹ ara wọn,
àwọn ènìyàn mi sì ní ìfẹ́ sí èyí,
kí ni ẹ̀yin yóò ṣe ní òpin?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.