Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ní oṣù keje ọdún yìí ni Hananiah wòlíì kú.

Jeremiah 28:17 in English

Jeremiah 28:17 · Berean Standard Bible

And in the seventh month of that very year, the prophet Hananiah died.

Context

15Wòlíì Jeremiah sọ fún wòlíì Hananiah pé, “Gbọ́ ọ, Hananiah! Olúwa kò rán ọ, síbẹ̀, ìwọ jẹ́ kí orílẹ̀-èdè yìí gba irọ́ gbọ́. 16Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Mo ṣetán láti mú ọ kúrò nínú ayé, ní ọdún yìí ni ìwọ yóò kú nítorí o ti wàásù ọ̀tẹ̀ sí Olúwa.’ ” 17Ní oṣù keje ọdún yìí ni Hananiah wòlíì kú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.