Jeremiah 2:34
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Lórí aṣọ rẹ ni wọ́n bá ẹ̀jẹ̀ àwọn tálákà aláìṣẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ kò ká wọn mọ́ níbi tí wọ́n ti ń rùn wọlé. Síbẹ̀ nínú gbogbo èyí
Jeremiah 2:34 in English
Jeremiah 2:34 · Berean Standard Bible
Moreover, your skirts are stained with the blood of the innocent poor, though you did not find them breaking in. But in spite of all these things
Context
32Wúńdíá ha le gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,
tàbí ìyàwó ohun ọ̀ṣọ́ ìgbéyàwó rẹ̀?
Síbẹ̀, àwọn ènìyàn mi ti gbàgbé mi
ní ọjọ́ àìníye. 33Ìwọ ti jẹ́ ọlọ́gbọ́n tó nípa ọ̀rọ̀ ìfẹ́!
Àwọn obìnrin búburú yóò kẹ́kọ̀ọ́ nípa ọ̀nà rẹ. 34Lórí aṣọ rẹ ni wọ́n bá
ẹ̀jẹ̀ àwọn tálákà aláìṣẹ̀,
bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ kò ká wọn mọ́ níbi tí wọ́n ti ń rùn wọlé.
Síbẹ̀ nínú gbogbo èyí 35ìwọ sọ wí pé, ‘Èmi jẹ́ aláìṣẹ̀;
kò sì bínú sí mi.’
Èmi yóò mú ìdájọ́ mi wá sórí rẹ
nítorí pé ìwọ wí pé, ‘Èmi kò dẹ́ṣẹ̀.’ 36Èéṣe tí ìwọ fi ń lọ káàkiri
láti yí ọ̀nà rẹ padà?
Ejibiti yóò dójútì ọ́
gẹ́gẹ́ bí i ti Asiria.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.