Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Bákan náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá wí pé:

Jeremiah 16:1 in English

Jeremiah 16:1 · Berean Standard Bible

Then the word of the LORD came to me, saying,

Context

1Bákan náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá wí pé: 2“Ìwọ kò gbọdọ̀ ní ìyàwó, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ ní ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin níbí yìí.” 3Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí nípa ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin tí wọ́n bá bí nílẹ̀ yìí, àti ìyá tí ó bí wọn àti baba wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.