Jeremiah 13:25
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èyí ni ìpín tìrẹ; tí mo ti fi sílẹ̀ fún ọ,” ni Olúwa wí, “Nítorí ìwọ ti gbàgbé mi o sì gbẹ́kẹ̀lé àwọn ọlọ́run àjèjì.
Jeremiah 13:25 in English
Jeremiah 13:25 · Berean Standard Bible
This is your lot, the portion I have measured to you,” declares the LORD, “because you have forgotten Me and trusted in falsehood.
Context
23Ǹjẹ́ Etiopia le yí àwọ̀ rẹ̀ padà?
Tàbí ẹkùn lè yí àwọ̀ rẹ̀ padà?
Bí èyí kò ti lè rí bẹ́ẹ̀
náà ni ẹ̀yin tí ìwà búburú bá ti mọ́ lára kò lè ṣe rere. 24“N ó fọ́n ọn yín ká bí i ìyàngbò
tí ẹ̀fúùfù ilẹ̀ aṣálẹ̀ ń fẹ́. 25Èyí ni ìpín tìrẹ;
tí mo ti fi sílẹ̀ fún ọ,”
ni Olúwa wí,
“Nítorí ìwọ ti gbàgbé mi
o sì gbẹ́kẹ̀lé àwọn ọlọ́run àjèjì. 26N ó sí aṣọ lójú rẹ,
kí ẹ̀sín rẹ le hàn síta— 27ìwà àgbèrè àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́,
àìlójútì panṣágà rẹ!
Mo ti rí ìwà ìríra rẹ,
lórí òkè àti ní pápá.
Ègbé ni fún ọ ìwọ Jerusalẹmu!
Yóò ti pẹ́ tó tí o ó fi máa wà ní àìmọ́?”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.