Isaiah 37:34
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nípa ọ̀nà tí ó gbà wá náà ni yóò padà lọ; òun kì yóò wọ inú ìlú yìí,” ni Olúwa wí.
Isaiah 37:34 in English
Isaiah 37:34 · Berean Standard Bible
He will go back the way he came, and he will not enter this city,’ declares the LORD.
Context
32Nítorí láti Jerusalẹmu ni àwọn àṣẹ́kù yóò ti wá,
àti láti òkè Sioni ni ikọ̀ àwọn tí ó sálà.
Ìtara Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni yóò mú èyí ṣẹ. 33“Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí nípa ọba Asiria,
“Òun kì yóò wọ ìlú yìí wá
tàbí ta ẹyọ ọfà kan níhìn-ín
Òun kì yóò wá síwájú rẹ pẹ̀lú asà
tàbí kí ó kó dágunró sílẹ̀ fún un. 34Nípa ọ̀nà tí ó gbà wá náà ni yóò padà lọ;
òun kì yóò wọ inú ìlú yìí,”
ni Olúwa wí. 35“Èmi yóò dáàbò bo ìlú yìí èmi ó sì gbà á là,
nítorí mi àti nítorí Dafidi ìránṣẹ́ mi!” 36Lẹ́yìn náà ni angẹli Olúwa jáde lọ ó sì pa ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án ó lé ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (185,000) ènìyàn ní i ibùdó àwọn Asiria. Nígbà tí àwọn ènìyàn yìí jí ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì gbogbo wọn ti dòkú!
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.