Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa ti dá ọ̀pá ìkà náà, ọ̀pá àwọn aláṣẹ,

Isaiah 14:5 in English

Isaiah 14:5 · Berean Standard Bible

The LORD has broken the staff of the wicked, the scepter of the rulers.

Context

3Ní ọjọ́ tí Olúwa yóò fi ìtura fún un yín kúrò nínú ìpọ́njú àti ìyà àti ìdè ìkà, 4ẹ ó sì fi ọ̀rọ̀ àbùkù yìí kan ọba Babeli pé, báwo ni amúnisìn ṣe wá sí òpin! Báwo ni ìbínú rẹ̀ ṣe parí! 5Olúwa ti dá ọ̀pá ìkà náà, ọ̀pá àwọn aláṣẹ, 6èyí tí ó ti lu àwọn ènìyàn bolẹ̀ pẹ̀lú ti kò dáwọ́ dúró, nínú ìrunú ni ó ṣẹ́gun àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú ìgbónára tí kò lópin. 7Gbogbo ilẹ̀ ni ó wà ní ìsinmi àti àlàáfíà, wọ́n bú sí orin.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.