Isaiah 11:1
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èèkàn kan yóò sọ láti ibi kùkùté Jese, láti ara gbòǹgbò rẹ̀ ni ẹ̀ka kan yóò ti so èso.
Isaiah 11:1 in English
Isaiah 11:1 · Berean Standard Bible
Then a shoot will spring up from the stump of Jesse, and a Branch from his roots will bear fruit.
Context
1Èèkàn kan yóò sọ láti ibi kùkùté Jese,
láti ara gbòǹgbò rẹ̀ ni ẹ̀ka kan yóò ti so èso. 2Ẹ̀mí Olúwa yóò sì bà lé e,
ẹ̀mí ọgbọ́n àti ti òye,
ẹ̀mí ìmọ̀ràn àti ti agbára,
ẹ̀mí ìmọ̀ àti ti ìbẹ̀rù Olúwa. 3Òun yóò sì ní inú dídùn nínú ìbẹ̀rù Olúwa.
Òun kì yóò ṣe ìdájọ́ pẹ̀lú ohun tí ó fi ojú u rẹ̀ rí,
tàbí pẹ̀lú ohun tí ó fi etí i rẹ̀ gbọ́,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.