Isaiah 10:31
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Madmena ti fẹsẹ̀ fẹ́ ẹ, àwọn ènìyàn Gebimu ti fi ara pamọ́.
Isaiah 10:31 in English
Isaiah 10:31 · Berean Standard Bible
Madmenah flees; the people of Gebim take refuge.
Context
29Wọ́n ti rékọjá ọ̀nà, wọ́n wí pé,
“Àwa ó tẹ̀dó sí Geba lóru yìí.”
Rama mì tìtì
Gibeah ti Saulu sálọ. 30Gbé ohùn rẹ sókè, ìwọ ọmọbìnrin Galimu!
Dẹ etí sílẹ̀, ìwọ Laiṣa!
Ìwọ òtòṣì Anatoti! 31Madmena ti fẹsẹ̀ fẹ́ ẹ,
àwọn ènìyàn Gebimu ti fi ara pamọ́. 32Ní ọjọ́ yìí, wọn yóò dúró ní Nobu
wọn yóò kan sáárá,
ní òkè ọmọbìnrin Sioni
ní òkè Jerusalẹmu. 33Wò ó, Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,
yóò kán ẹ̀ka náà sọnù pẹ̀lú agbára.
Àwọn igi ọlọ́lá ni a ó gé lulẹ̀
àwọn tí ó ga gogoro ni a ó rẹ̀ sílẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.